FIRST TERM EXAMINATION
SUBJECT: YORUBA LANGUAGE L1 CLASS: JSS 1
DURATION: 2 HOURS
Akiyesi Pataki: Jowo fi ara bale ka awon ibeere wonyii daradara ki o si mu
idahun ti o tona ninu abala A ati B.
ABALA A: Ibeere ewonidahun (Objective Questions)
Ka itan yii daradara ki o si mu idahun ti o tele e
ITAN OPOLO ATI AKUKO
Ni aye atijo’ awon ore meji kan wa. Oruko okan ni Opolo, oruko ekeji ni Akuko .
Akuko so fun ore re wi pe ki o tele oun lo si ile ana oun .Bi won ti de oju ona ni Opolo
dabaa wi
pe ki awon se ayipada aso awon.Bayii ni Opolo gba aso akuko wo ti Akuko naa gba
aso Opolo wo. Bi won ti de ibe ni won bere sii pon won le ti won n pon won ti won si n
ge won.
Lehin ti won ti jeun ekeji tan ni won pe Opolo ti won ro wi pe Akuko ni, ti won fa
iyawo le e lowo.
Inu Akuko to wa ninu aso Opolo ko dun rara; fun idi eyi, o fi orin bonu o bere sii wi
pe:
Opolo gbawo mi wo ------------ saworo,
O gbawo mi wo ------------ saworo,
Kunbete kunbete ------------ saworo,
Kunbete---- kunbete ------------ saworo,
Bayii ni awon eniyan teti si orin ti Akuko to ti wa ninu aso Opolo n ko, ti won bo aso
kuro lorun re ti won si da awo re pada.Ojukokoro ko dara rara.
1. Awon meloo ni won jo n se ore ninu itan yii?
A.Awon mefa B.Awon meji C.Awon merin D.Awon meedogun
2. Ta lo be enikeji re lati lo si ile ana re?
A.Opolo B.Akuko C.Saworo D.Kubete
3 Iru aba wo ni opolo da fun ore re?
A.wi pe ki awon maa korin B.wi pe ki won maa rin C.wi pe ki awon paaro aso
awon D.pe ki awon maa jo
4. Ki ni won se fun won nigba ti won de ile ana re?
A.won pon won le B.won n bu won C.won n lu won D.won n sa won
5. Ta lo bere sii korin?
A.Akuko B.Opolo C.Ojola D.Olumomi
6. Iru orin wo ni won o n ko?
A.Orin aro tabi orin ekun B.Orin olomowewe C.Orin abolomokuuya D.Orin nla
7. Ki lo faa ti o fi n ko orin yii?
A.won yan eni naa je ni B.won ko egba bo eni naa ni C.won gba ewu tabi aso
eni naa ni D.won fee pa eni naa ni
8. Iru ore wo ni opolo ?
A.ore rere B.ore olojukokoro C.ore to moore D.ore kekere
9. Eko wo ni itan yii ko wa?
A.Ki a maa ya aso alaso B.Ki a ma se se ojukokoro nnkan elomiiran C.Ki a
mase ni ore D.Ki a maa lo ile ana eni
10. Akole wo ni o ba itan yii mu?
A.Itan iyawo opolo B.Akuko fe na opolo C.Opolo ma darao D.Itan opolo ati
akuko
11. Leta meloo lo wa ninu alifabeeti ede Yoruba?
A.meje B.merin C.marun D.meedogbon
12. Faweli akoko ni A.o B.a C.e D.u
13. Leta ti o gbeyin ninu alifabeeti ede Yoruba ni A.y B.p C.r D.f
14. Ewo ni ko si lara faweli aranmupe ninu iwonyii?A.on B.en C.in D.pi
15. Meloo ni faweli airanmupe? A.meje B.mesan C.meedogun D.ogun
16. Ege oro ti o kere ju ti o si le gba ami sori ni a mo si
A.afo B.silebu C.egero D.afomo
17. Baba nla awon Yoruba ni a n pe ni
A.Oranmiyan B.Oyalabi C.Oduduwa D.Agbonmifegun
18. Nibo ni ogun ti le awon iran Yoruba kuro ?
A .Ilu-meka B.Gogobiri C.Kaduna D.Idahomi
19. Nibo ni iran Yoruba tedo si lati ibi ti won ti n bo?
A.Ibadan B.Ile-ife C.Akure D.Ibariba
20. Taa ni won ba ni ilu Ile-ife?
A.Oranmiyan B.Agbonmiregun C.Moremi D.Lisabi
Want more Objective Questions like this?
Get the Complete Yoruba Language L1 or L2 Exam Questions (Obj & Theory); In
editable Ms-word format for any of the Junior Secondary School 1 – 3 Classes.
Continue Reading to Know How
ABALA KEJI PART B
DAHUN IBEERE AKOKO (QUESTION 1) ATI MEJI MIRAN
1 a.Tun awon oro wonyii ko pelu akoto ode oni.
i. Aiye ii.Eiye iii.Enia iv.Oshogbo v.Offa vi.Otta vii.Nigbati viii.Nibiti
ix.Nwon x.Pepeiye
b. Ko gbogbo faweli aranmupe sile.
2 a. Ko awon igbese akoko marun ti o se Pataki ninu eto igbeyawo sile.
b. Ko awon ohun elo idana marun (items of engagement) ni ibi igbeyawo sile.
3. a. Daruko Ilu marun ati ounje ti won feran lati maa je.
b. Daruko ipinle Yoruba kan ati eka ede marun ti a le ri ni ipinle naa.
4. a. Ko iwulo ede marun
b. Ko awon nomba wonyii ni ede Yoruba. i.10 ii15 iii 20 iv.40 v.50
Yoruba Language L1 & L2 Exam Questions
for JSS 1-3
To get the complete exam question papers for the subject and any of the classes
concern, then continue reading
How to Get Junior Secondary School Yoruba Language Exam Questions
Step to get Yoruba L1 or L2 Exam Questions for JSS 1 – 3
1. MAKE A CALL.
Call or Whatsapp us on 08051311885 for cost and account number to make
payment and how to received your Ms-Word/PDF Copy
2. MODE OF PAYMENT.
Mobile Transfer, POS or Direct Bank Deposit.
3. AFTER PAYMENT.
Send us the following
Depositor Name:
Name of Product Paid for:
Valid email address.
4. DELIVERY ASSURANCE.
We will deliver the past question to you, 10 minutes after confirmation of
payment to the email address you will send to us.
Also available for download are other primary school subjects and exam questions
Interested in getting JSS 1, 2, 3 (Upper Basic) Past Question in PDF or
Ms-Word Format for 1st, 2nd, 3rd Term for any of the following Subjects:
1. English Studies.
2. Mathematics.
3. Basic Science and Technology. (Basic Science, Basic Technology,
Computer Studies/ICT, Physical and Health Education)
4. Religion and National Values (Christian Religious Studies, Islamic
Religious Knowledge, Social Studies, Civic Education, Security
Education).
5. Cultural and Creative Arts. (Music, Drama and Craft)
6. Business Studies.
7. Nigerian Languages. (Yoruba, Hausa, Igbo)
8. Pre-vocational Studies (Home Economics, Agriculture Science).
9. French.
10. Arabic.
ALSO AVAILABLE
WAEC Past Questions
NECO Past Questions
NABTAB Past Questions
Post-UTME Past Questions
School of Nursing Past Questions
Nigeria Navy Past Questions,
POLAC PAST QUESTIONS
TRCN Past Questions and Answers
Download Free Past Questions
Primary School Leaving Certificate Exam Past Questions
NCEE Past Questions
Recruitment Past Questions
SEARCH TAG
Yoruba Questions for Junior Secondary School,
Yoruba Exam Questions for JSS,
Yoruba Objective Questions,
JSS Yoruba Language Exam Questions,