Chief (Mrs) Eunice
BOLATITO
DOKUN
TURNS
60
Wednesday
16TH JUNE, 2021
Order of Program
1. Opening Hymn
2. Opening Prayer
3. Praise &Worship
4. Bible Reading
5. Exhortation
6. Thanksgiving Hymns
7. Prayer for the Celebrant
8. Closing Hymn
9. Closing Prayer
10.Vote of Thanks
11. Cutting of the Cake
3
OPENING HYMN – OKAN Anu Re, yi aye ka
MI YIN OBA ORUN
4. Angel, e ju mo ba
1. Okan mi yin Oba orun wabo
Mu ore wa sodo re Eyin nri loju koju
'Wo ta wosan, t'adariji Orun, Osupa, e wole
Tal'aba ha yin bi Re ? Ati gbogbo agbaye
Yin Oluwa, yin Oluwa E bawa yin, e bawa yin
Yin Oba ainipekun Olorun Olotito.
2. Yin fun aanu t'oti fi han
F'awon Baba 'nu ponju
Yin L Okan naa ni titi
O lora lati binu
Yin Oluwa, yin Oluwa
Ologo n'u otito
3. Bi baba ni O ntojuwa
O si mo ailera wa
Jeje l'o n gbe wa lapa Re
O gba wa lowo ota
Yin Oluwa, yin Oluwa
4
THANKSGIVING HYMN E korin Aleluya s'Oba
mimo
1.Eba wa yin Oluwa Eni ba more Jesu k'oba
Hallelujah! wa gbega.
Eni ba more Jesu k'o ba
wa gbega, 3. Eni t'O npa wamo o,
E bawa yin Oluwa, lojojumo,
Aleluya! Eni t'O nyo wa ninu ewu
Eni ba more Jesu k'oba gbogbo,
wa gbega Eni t'O npa Israeli mo k'i
i togbe;
Eni ba more Re k'oba wa Eni ba more Jesu k'oba
gbega wa gbega.
Eni ba more Re k'oba wa
gbega 4. Eni t'O npese fun aini
E bawa yin Oluwa, wa l'aye,
Aleluya! Eni t'O nsore fun wa l'ojo
Eni ba more Jesu k'oba gbogbo,
wa gbega Ore t'O nse fun wa ko
l'onka rara;
2. Eni t'O f'orun sile t'O Eni ba more Jesu k'o ba
wa s'aye, wa gbega.
Lati ku fun ese araye Amin.
gbogbo;
55
THANKSGIVING HYMN 2. E yin fun 'rapada ti
EYIN OBA OGO OHUN NI gbogbo okan
OLORUN E yin fun orisun
imularada
1. Eyin Oba ogo, On ni Fun inu rere ati itoju re
Olorun Fun 'daniloju pe O ngbo
Yin fun 'se 'yanu ti o ti adura
fihan
O wa pelu awon ero 3. E yin fun idanwo bi
mimo l'ona okun ife,
O si je imole won l'osan T'o nso wa po mo awon
l'oru. ohun orun
E yin Angel 'didan, lu Fun 'gbagbo ti n”segun ,
duru wura 'reti ti kisa
Ki gbogbo yin juba, t'e n Fun ile ogo t'O ti pese fun
wo oju re wa.
Ni gbogbo 'joba re, b'aye
ti nyi lo
Ise re y'o ma yin
Ise re y'o ma yin
Fi ibukun fun Oluwa
okan mi.
66
THANKSGIVING HYMN Emi Re nto, o sin se 'tunu
OKAN MI YO NINU O mba mi lo si 'bikibi
OLUWA
4. Emi y'o dabi Re ni 'jo
1. Okan mi nyo ninu kan
Oluwa Un o s'eru wuwo mi kale
'Tori O je iye fun mi Titi di 'gbana un o s'oloto
Ohun Re dun pupo lati Ni sise oso f'ade Re.
gbo Amin
Adun ni lati r'oju Re
Emi nyo ninu Re
Emi nyo ninu Re
Gba gbogbo lo fayo kun
okan mi
'Tori emi nyo n'nu Re.
2. O tipe t'O tin wa mi
kiri
'gba ti mo rin jina s'agbo
O gbe mi wa sile l'apa Re
Nibi ti papa tutu wa
3. Ire at'anu Re yi mi ka
Or'ofe Re nsan bi odo
77
THANKSGIVING HYMN 3. Nibo l'a ko le gbe I'aye
BI KRISTI DA OKAN MI L'or'oke tabi petele
NDE L'ahere tabi agbala,
Kos'ewu, Jesu wa nibe.
1. Bi Krist'ti da okan mi Aleluya! Ayo l'o je
nde Pe, mo tiri 'dariji gba.
Aye mi ti dabi orun, Ibikibi ti mo bawa
Larin 'banuje at'aro Ko s'ewu, Jesu wa nibe.
Ayo ni lati mo Jesu,
8
Aleluya! Ayo l'o je
Pe, mo tiri 'dariji gba.
Ibikibi ti mo bawa
Ko s'ewu, Jesu wa nibe.
2. Mo ti ro pe orun jinna
Sugbon nigba ti Jesu de
L'orun ti de 'nu okan mi,
Nibe niy'o si wa titi.
Aleluya! Ayo l'o je
Pe, mo tiri 'dariji gba.
Ibikibi ti mo bawa
Ko s'ewu, Jesu wa nibe.
THANKSGIVING HYMN Ti mo ti fe sile
MO TI NI JESU LORE O si f’agbara re gbe okan
mi ro
1. Mo ti ni Jesu lore Bi aye tile ko mi
O j’ohun gbogbo fun mi Ti satan’ dan mi wo
Oun nikan larewa ti okan mi Jesu yo mumi dopin irin mi
fe Oun n’itanna ipado
Oun ni tanna ipado Irawo owuro
Oun ni enikan naa Oun nikan l”Arewa ti okan
To le we mi nu kuro nin’ese mi fe
mi 3. Oun ki yo fi mi sile
Be k’yo ko mi nihn
Olutunu mi loje Niwon ti nba fi gbagbo
Ni gbogbo wahala pofin re mo
Oun ni ki n kaniyan mi O jodi na yi mi ka
l’Oun lori N k’yo beru keru
Oun n’itanna ipado Yo fi manna re bokan mi
Irawo owuro tebi npa
Oun nikan l’Arewa ti okan Gba m’ba dade nikeyin
mi fe N’o roju bukun re
2. O gbe gbogbo banuje mi Ti adun re yo ma san titi lai
at’irora mi ru Oun n’itanna ipado
O j’odi agbara mi nigba Irawo owuro
danwo Oun nikan l’Arewa ti okan
Tori re mo k’ohun gbogbo mi fe
99
THANKSGIVING HYMN 3. Iwo to nf'agan lomo to
npe ranse
IWO TO FE WA LA O MA Ninu ola re to ga
SIN TITI Eni t'oti s'alaileso si dupe
Fun 'se ogo ola re
1. Iwo to fe wa la o ma
sin titi 4. Eni t'ebi npa le ri ayo
Oluwa Olore wa ninu
Iwo to n so wa n'nu Agbara nla re to ga
idanwo aye Awon to ti nwo ju re fun
Mimo, logo ola re aanu
Won tun nyo n'nu ise re.
Baba, iwo l'a o ma sin
Baba, iwo l'a o ma bo 5. F'alafia re fun ijo re
Iwo to fe wa l'a o ma sin l'aye
titi K'ore-ofe re ma ga;
Mimo l'ogo ola re. k'awon eni tire ko ma yo
titi
2. Iwo to nsure s'ohun ninu ogo ise re. Amin.
t'agbin s'aye
T'aye fi nrohun je o
Awon to mura lati ma
s'ooto
Won tun nyo n'nu ise re.
10
THANKSGIVING HYMN 3. Majemu ati eje re
IGBAGBO MI DURO LORI L’emi o ro mo b’ikunmi de
Gbati ko sa tileyin mo
1.Igbagbo mi duro lori O je ireti nla fun mi
Eje atododo Jesu
N’ko je gbekele ohun kan Mo duro le Krist’ Apata
Leyin oruko nla Jesu Ile miran iyanrin ni
Mo duro le Krist’ Apata
Mo duro le Krist’ Apata Ile miran iyanrin ni
Ile miran iyanrin ni
Mo duro le Krist’ Apata 4. Gbat’ipe kehin ba si dun
Ile miran iyanrin ni A! m ba le wa ninu Jesu
Ki nwo ododo re nikan
2. B’ire ije mi tile gun Ki n duro niwaju ite
Orofe re ko yi pada
Bo ti wu kiji naa leto Mo duro le Krist’ Apata
Idakoro mi ko ni ye Ile miran iyanrin ni
Mo duro le Krist’ Apata
Mo duro le Krist’ Apata Ile miran iyanrin ni
Ile miran iyanrin ni
Mo duro le Krist’ Apata
Ile miran iyanrin ni
1111
CLOSING HYMN 4. Ore ofe ko mi
OREOFE OHUN ADUN Bi a ti 'gbadura
O pa mi mo titi d'oni
1. Ore ofe ohun Kosi je ki n sako
Adun ni l'etiwa
Gbohungbohun re y'ogba 5. Je k'ore ofe yi
orun kan F'agbara f'okan mi
Aye y'ogbo pelu Ki nle fi gbogbo ipa mi
At'ojo mi fun O. Amin
Ore ofe sa
N'igbekele mi
Jesu ku fun araye
O ku fun mi pelu
2. Ore ofel'oko
Oruko mi l'orun
L'o fi mi fun Od'agutan
T'O gba iya mi je.
3. Ore ofe to mi
S'onaalafia
O ntoju mi l'ojojumo
Ni irin ajo mi
1122
APPRECIATION
Dearly beloved, thank you for celebrating the diamond jubilee
and milestone birthday with me.
Thank you for your love, presence and gifts.
Thank you for honouring the anointing of God upon my life.
I express special thanks to my family, friends and loved ones.
God will honour and favour you greatly, words are not enough
to appreciate you all, you’re the best
Chief (Mrs)
Eunice Bolatito Dokun