The words you are searching are inside this book. To get more targeted content, please make full-text search by clicking here.

Cover_page_of_the_program_big_

Discover the best professional documents and content resources in AnyFlip Document Base.
Search
Published by niyiolu2000, 2021-03-29 02:55:25

Brother @70

Cover_page_of_the_program_big_

Programe

OEf vents

ThanksgivingIn praising God with

KUYEADESOJI OLORUNFUNMI

@ His

Celebration

SUNDAY,
APRIL 18, 2021

@ 7.30 AM

ST. BARNABAS’
ANGLICAN CHURCH,

OKUN-OWA, IJEBU

Celebration

KUYEADESOJI OLORUNFUNMI

For through wisdom
your days will be many,
and years will be added

to your life.
Proverbs 9:11 (NIV)

DIOCESE OF IJEBU SOUTH/WEST

ORDER

Of Service for Holy Communion

thanksgivingIn praising God with

KUYEADESOJI OLORUNFUNMI

@ His

Celebration

SUNDAY, APRIL 18, 2021
@ 7.30 AM

Eto Isin Idapo Mimo ati Idupe Ojo Ibi Adorin Odun
Ti a se ni Ojo Sunday, Ojo Kejinlogun, Osu Kerin, Odun 2021
ni Dede Ago Meje abo ni owuro

Brother G.T. Oshinaike Mr. Adetola Okuneye Sister C. O. Popoola
Aare Egbe Mr. J.O. Adebunkunola Akowe Egbe

Mr. Oluwafemi Boyejo Awon Agbopa Alufa Mr. Yomi Awoniyi
Organist Revd M. O. Idowu Choir Master
Revd Can. E. O. Ojo
Mr. Sanya Odukoya Awon Oluranlowo Alufa Mrs. C. T. Popoola
Iriju Ijo Iriju Alufa

Venerable Olawale O. Igbalajobi, M. A, B. A (Hons) Dip Th.
Alufa Ijo Ati Archdeacon Okun-Owa Archdeaconry

The Rt. Revd Dr. B.F. R. Ogunbanwo Ph. D (UKZN), FICT, FALI, JP

The Lord Bishop of Ijebu South/West

01

DIOCESE OF IJEBU SOUTH/WEST

Eto Isin 1. Orin Akowole I.O. M. 556
Idapo Mimo 2. Isin Idapo Mimo (Apa Kini)
ati Idupe Ojo 3. Adura Kukuru fun Ojo Ibi
Ibi Adorin Odun 4. Saamu 30
5. Episteli: Fillipi 4: 4-9
KUYEADESOJI OLORUNFUNMI 6. Orin: Olorun Aye Mi
7. Ihinrere: Johannu 15: 1-9
@ His 8. Orin: I.O. M. 340 (Covenant of Faint)
9. Iwaasu
Celebration 10. Orin I.O. M. 121 (Development Collection)
11. Igbagbo Nikea titi de Ikini Alaafia
Ti a se ni Ojo Sunday, 12. Orin: Great is Thy Faithfulness
Ojo Kejinlogun, 13. Adura Iyasimimo
14. Orin fun Ipinfunni: I.O. M. 313, 438, 436
Osu Kerin, Odun 2021 15. Orin fun Ipalemo: I.O.M 341
ni Dede Ago Meje abo 16. Adura Lehin Ipinfunni
17. Idupe- Olojo Ibi
ni owuro 18. Ifilo
19. Orin Diocese: I.O.M.98
20. Adura ati Ibukun
21. Orin Akojade: I.O.M. 309

ProgrameKUYEADESOJI OLORUNFUNMI
@ His
OEf vents
01 Celebration SUNDAY, APRIL 18, 2021 @ 7.30 AM

ST. BARNABAS’ ANGLICAN CHURCH, OKUN-OWA, IJEBU

1. ORIN AKOWOLE I. O. M. 556 - FUN ANU TO PO B’IYANRIN

1. Fun anu to po b’iyanrin, 3. Eyi l’ohun t’emi o se, 5. Emi ko le sin b’ o ti to,
Ti mo ngba l’ ojumo; F’ohun t’O se fun mi; Nko n’ise kan to pe;
Lati’odo Jesu Oluwa, Em’o mu ago igbala, Sugbon em’o sogo yi pe,
Kil’ emi o fi fun? Ngo kepe Olorun. Gbese ope mi po.
Amin.

2. Kini ngo fi fun Oluwa, 4. Eyi l’ope ti mo le da,
Lat’inu okan mi? Emi osi, are;
Ese ti ba gbogbo re je, Em’o ma soro ebun Re,
Ko tile jamo nkan. Ngo si ma bere si.

2. ISIN IDAPO MIMO (APA KINI)

3. ADURA KUKURU FUN OJO IBI

4. SAAMU 30

1. EMI o kokiki re, Oluwa; nitori iwo li o gbe mi leke, ti iwo ko si je ki awon ota mi ki o yo mi
2. Oluwa Olorun mi, emi kigbe pe o, iwo si ti mu mi lara da.
3. Oluwa, iwo ti yio okan mi jade kuro ninu isa-oku; iwo o si pa mi mo laye, ki emi ki o ma ba lo

sinu iho.
4. Korin si Oluwa, Enyin enia re mimo, ki e si ma dupe ni iranti iwa-mimo re.
5. Nitoripe, ni iseju kan ni ibinu re ipe, li Ojurere re ni iye gbe wa; bi ekun pe di ale kan, sugbon ayo
` mbo li owuro.
6. Ati ninu alafia mi, emi ni ipo mi yio pada lailai.
7. Oluwa, nipa oju-rere re, iwo ti mu oke mi duro sinsin: nigbati iwo pa oju re mo, enu yo mi.

8. Emi kigbe pe o, Oluwa; ati si Oluwa li emi mbebe gidigidi.
9. Ere kili o wa li eje mi, nigbati mo ba lo sinu iho? erupe ni yio ma yin o bi? on ni yio ma soro

otito
re bi?
10. Gbo Oluwa, ki o si sanu fun mi: Oluwa, iwo ma se oluranlowo mi.
11. Iwo ti so ikanu mi di ijo fun mi; iwo ti boa so-ofo mi kuro, iwo si fi ayo di mi li amure.
12. Nitori idi eyi ni ki ogo mi ki o le ma korin si o, ki o ma si se dake. Oluwa Olorun mi emi o ma fi
iyin fun o lailai.

5. EPISTELI: FILLIPI 4: 4-9

4. E ma yo ninu Oluwa nigbagbogbo: mo si tun wi, E ma yo.
5. E je ki ipamora nyin di mimo fun gbogbo enia, Oluwa mbe nitosi.
6. E mase aniyan ohunkohun; sugbon ninu ohun gbogbo, nipa adura ati ebe pelu idupe, e ma

fi ibere nyin han fun Olorun.
7. Ati alafia Olorun, ti o ju imoran gbogbo lo, yio so okan ati ero nyin ninu Kristi Jesu,
8. Li akotan, ara, ohunkohun ti ise owo, ohunkohun ti ise tito, ohunkohun ti ise mimo,

ohunkohun ti
ise fife, ohunkohun ti o ni irohin rere; bi iwa tito kan ba wa, bi iyin k aba si wa, e ma gba nkan
wonyi ro.
9. Nkan wonni, ti enyin ti ko, ti enyin si ti gba, ti enyin si ti gbo, ti enyin si ti ri lowo mi, e ma se
won: Olorun Alafia yio si wa pelu nyin.

6. ORIN: OLORUN AYE MI 3. Gbogbo pa emi mi
Yo je ire nikan
1. Olorun aye mi Gbogbo akoko mi
Emi mi yo si O Maa ya soto fun O
Ore Re l'o da mi Jo tun mi bi laworan Re
Ayajo Ibi mi tun de Ngo si ma yin O titi aye
Ngo sure f'ojo ta bi mi
4. Mo fe se ife Re
2. Ni gbogbo ojo mi B'angeli ti nse lorun
Kin wa laye fun O Ki n datunbi ninu Kristi
Ki gbogbo emi mi Ki n n'dariji gba
F'ope, iyin fun O Mo n'fe mufe pipe Re se
Gbogbo ini ati iwa mi Kife Re ya mi si mimo. Amin
Yo yin Eleda mi logo

7. IHINRERE: JOHANNU 15: 1-9

1. Emi ni ajara toto, Baba mi si ni olusogba.
2. Gbogbo eka ninu mi ti ko ba so eso, on a mu u kuro: gbogbo eka ti o ba si so eso, on a we e mo,

ki o le so eso, si i.
3. Enyin mo nisisiyi nitori oro ti mo ti so fun nyin.
4. E ma gbe inu nyin. Gege bi eka ko ti le so eso fun ara re, bikosepe o ba ngbe inu ajara, beli

enyin, bikosepe e ba ngbe inu mi.
5. Emi ni ajara enyin li eka. Eniti o ngbe inu mi, ati emi ninu re, on yio so eso opolopo: nitori ni yiyara

nyin kuro lodo mi, e ko le se ohun kan.

6. Bi enikan ko ba gbe inu mi, a gbe e sonu gege bi eka a si gbe; nwon a si ko won jo, nwon a si so
won sinu ina, nwon a si jona.

7. Bi enyin ba ngbe inu mi, ti oro mi ba si ngbe inu nyin, e o bere ohunkohun ti e ba fe, a o si se e
fun nyin.

8. Ninu eyi li a yin Baba mi logo pe, ki enyin ki o ma so eso pupo; enyin o si je omo ehin mi.

9. Gege bi Baba ti fe mi, beli emi si fe nyin: e duro ninu ife mi.

8. ORIN: I.O. M. 340 - JESU OLUWA, OBA MI (COVENANT OF FAINT)

1. Jesu Oluwa, Oba mi, 3. Jesu, kil’ o ri ninu mi,
Gbohun mi nigbati mo npe, Ti ’fe na fi po to bayi?
Gbohun mi lati ’bugbe Re, Ore Re si mi tip o to!
Rojo ore- ofe sile; O ta gbogbo ero mi yo!
Oluwa mi, mo feran Re, Oluwa mi, &c.
Je ki nle ma feran Re si.
4. Jesu, ’Wo o je, orin mi,
2. Jesu, mo ti jafara ju, Tire l’ aiya at’ okan mi:
Ngo se le fe O b’o ti ye? Tire ni gbogbo ini mi,
Em’ o se le gb’ ogo Re ga, Olugbala, ’Wo ni temi:
Ati ewa oruko Re. Oluwa mi, mo feran Re,
Oluwa mi. &c. Je ki nle ma feran Re si. Amin.

9. IWAASU

10. ORIN I.O. M. 121 - OLORUN MI BOJUWO MI (DEVELOPMENT COLLECTION)

1. Olorun mi bojuwo mi 3. Oluwa tal’ o ridi Re,
F’ iyanu ’fe nla Re han mi; Iwo Olorun ologo ?
Ma je ki ngbero fun’ ra mi, Iwo l’ egbegberun ona,
Nibi ti nko ni ’kansoso.
’ Tori ’Wo ni ngbero fun mi; Baba mi, &c.
Baba mi, to mi l’ aiye yi,
Je ki ’gbala Re to fun mi. 4. B’ orun ti ga ju aiye lo
Beni ’ro Re ga ju t’ emi;
2. Ma je ki mbu le O lowo, Ma dari mi k’ emi le lo
’Tori ’Wo li onipin mi; S’ ipa ona ododo Re.
S’ eyi ti ’Wo ti pinnu re, Baba mi, &C. Amin
Iba je ponju tab’ ogo.
Baba mi, &c.

11. IGBAGBO NIKEA TITI DE IKINI ALAAFIA

IJEWO IGBAGBO TI NIKEA
(Ijo yoo dide duro)

Ijo: A gba Olorun kan gbo,

Baba Olodumare,
Eledaa orun oun aye,
ati ohun gbogbo ti a n ri, ati eyi ti a ko ri.
A gba Oluwa kan gbo. Jesu Kristi,
Omo kansoso naa ti Olorun,

ti a bi lati ayeraye lati odo Baba.
Olorun lati inu Olorun, Imole lati inu Imole,
Olorun tikarare lati inu Olorun tikarare,
Eni ti a bi ti a ko da,
ti ise ara kan naa pelu Baba.
Nipa Re ni a da ohun gbogbo,
Nitori awa eniyan, ati fun igbala wa,
O sokale lati orun wa;
Nipa agbara Emi Mimo, O mu awo ara nipase
Maria Wundia, O si di eniyan.
Nitori wa, a ti owo Pontiu Pilatu kan an mo
igi agbelebu;
O jiya iku, a si sin in.
Ni ojo keta, O tun jinde gegebi Iwe Mimo ti soo;
O goke re orun, O si jokoo l’owo otun Baba,
yoo si tun pada wa ninu ogo lati wa se idajo
alaye ati oku, ijoba Re ki yoo nipekun.
A gba Emi Mimo gbo, Oluwa, Olufunni ni iye,
Eni ti o ti odo Baba ati Omo wa, Eni ti a
Sin ti a si n yin logo po pelu Baba ati Omo.
Eni ti o ti soro lati enu awon Wolii, a
gba ijo kansoso, Ijo Mimo, Ijo ti o kari
aye ti o ni eko awon Aposteli gbo, A jewo
baptisimu kan fun ifiji ese,
A n reti ajinde oku, ati iye aye ti nbo wa. Amin.

12. ORIN: GREAT IS THY FAITHFULNESS

1 Great is thy faithfulness, O God my Father
There is no shadow of turning with thee.
Thou changest not, thy compassions, they fail not.
As thou hast been thou forever wilt be.

Refrain:

Great is thy faithfulness!
Great is thy faithfulness!
Morning by morning new mercies I see.
All I have needed thy hand hath provided.
Great is thy faithfulness, Lord, unto me!

2. Summer and winter, and springtime and harvest,
Sun, moon, and stars in their courses above,
Join with all nature in manifold witness
To thy great faithfulness, mercy, and love.

(Refrain)

3. Pardon for sin and a peace that endureth,
Thine own dear presence to cheer and to guide,
Strength for today and bright hope for tomorrow;
Blessings all mine, with ten thousand beside!

(Refrain)

13. ADURA IYASIMIMO

14. ORIN FUN IPINFUNNI: I.O. M. 313 - IGBAGBO MI WO O

1. Igbagbo mi wo O, 3. ‘Gba mo nrin l’ okunkun,
Iwo Odaguntan, Ninu ibinuje;
Olugbala: S’ amona mi.
Jo gbo adura mi, M’ okunkun lo loni,
M’ ese mi gbogbo lo, Pa ‘banuje mi re,
K’ emi lat’ oni lo Ki nma sako kuro
Si je Tire. Li odo Re.

2. Ki ore- ofe Re 4. Gbati aiye ba pin,
F’ilera f’ okan mi. T’ odo tutu iku
Mu mi tara: Nsan lori mi;
B’ Iwo ti ku fun mi, Jesu, ninu ife,
A! k’ ife mi si O, Mu k’ifoiya mi lo,
K’ o ma gbona titi; Gbe mi d’ oke orun,
B’ina iye. B’okan t’a ra. Amin.

I.O. M. 438 - KIL’O LE W’ESE MI NU,

1. Kil’o le w’ese mi nu, 2. Fun ‘wenumo mi, nko ri 4. Gbogbo igbekele mi,
Ko si, lehin eje Jesu; Nkan mi, lehin eje Jesu; Ireti mi, l’ eje Jesu;
Ki l’o tun le wo mi san, Ohun ti mo gbekele Gbogbo ododo mi ni
Ko si, lehin eje Jesu. Fun ‘dariji, l’ eje Jesu. Eje, kiki eje Jesu.
A! eje yebiye A! eje ‘yebibye, &c. A! eje yebiye, &c. Amin..
T’o mu mi fun bi sno,
Ko s’isun miran mo, 3. Etutu f’ese ko si,
Ko si, lehin eje Jesu. Ko si, lehin eje Jesu;
Ise rere kan ko si,
Ko si, lehin eje Jesu.
A! eje ‘yebiye, &c.

I.O. M. 436 - OJO KO; ASE NA LEYI Titi l’a o ma je onje eyi 5. Sugbon nisisiyi, ago
K’ o to di igba na; Kikoro l’ em’ o mu,
3. Ka gbogb’ aiye l’ opolopo Emi o mu nitori nyin,
1. Ojo Ko; ase na leyi; Y’o ma je, y’o ma mu. Ago rora iku.

Mo f’ara mi fun nyin; ‘Bukun atorunwa y’o ma 6. E ko le mo banuje mi,
E wo, mo f’ eje mi fun nyin, Wa lor’ awon t’ o nje; E ko ti r’ogo mi;
Lati ran nyin pada. Ngo gbe or’ ite Baba mi Sugbon e ma s’eyi titi,
Ma pes’ aye fun won. K’e ma fir anti mi. Amin.
4.
2. O di ‘nu ‘joba Baba mi,

Ki mto tun ban yin mu;
‘Gbana ekun ko ni si mo,
A o ma yo titi.

15. ORIN FUN IPALEMO: I.O.M 341 - KI NFE O SI, KRISTI! KI NFE O SI

1. Ki nfe O si, Kristi! Ki nfe O si; 3. Je ki ‘banuje de, at’ irora,
Gb’ adura ti mo ngba lor’ ekun mi, Didun l’ ojise Re, at’ ise won.
Eyi ni ebe mi:- ki nfe O si, Kristi! ‘Gba nwon mba mi korin, ki nfe O si Kristi!
Ki nfe O si! Ki nfe O si! Ki nfe O si! Ki nfe O si!

2. Lekan,, ohun aiye ni mo ntoro; 4. Nje, opine mi mi y’o w’ iyin Re,
Nisisiyi, ‘Wo nikan ni mo nwa; Eyi ni y’o je oro kehin re:
Eyi l’ adura mi:- Ki nfe O si, Kristi ! Adura na o je:- Ki nfe O si Kristi !
Ki nfe O si! Ki nfe O si! Ki nfe O si! Ki nfe O si! Amin.

16. ADURA LEHIN IPINFUNNI

17. IDUPE- OLOJO IBI

18. IFILO

19. ORIN DIOCESE: I.O.M.98 - OLORUN BETEL, ENITI

1. Olorun Betel, eniti 2. A mu eje at’ ebe wa 3. Ninu idamu aiye yi,
O mbo awon Tire; Wa iwaju ‘te Re, Ma toju ipa wa;
Enit’ o mu baba wa la Olorun awon baba wa, Fun wa ni onje ojo wa,
Ojo aiye won ja. Ma je Olorun wa. At’ aso t’ o ye wa.

4. Na ojiji ‘ye Re bow a, 5. Iru ibukun bi eyi,
Tit’ ajo wa o pin, L’ a mbere lowo rE;
Ati ni ‘bugbe Baba wa, Iwo o je Olorun wa
Okan wa o simi. At’ ipin wa lailai. Amin.

20. ADURA ATI IBUKUN

21. ORIN AKOJADE: I.O.M. 309 - MO F’ EMI MI SABE

1. Mo f’ emi mi sabe 3. Ohun t’o wu k’o de,
Itoju Re Jesu; 4. Ife re ni nwon nse:
‘Wo ko jo mi l’ ainireti, Mo f’ ori pamo saiya Re,
‘Wo l’ Olorun Ife. Nko foiya iji yi.

2. ‘Wo ni mo gbekele B’ ibi tab’ ire de,
‘Wo ni mo f’ara ti: Y’o dara fun mi sa!
Rere at’ Otitio ni O, Ki nsa ni O l’ ohun gbogbo,
Eyi t’ O se l’ o to. Ohun gbogbo n’nu Re. Amin.

KUYEADESOJI OLORUNFUNMI

Celebration

Bioraphy
Picture Panorama
Happy Birthday
Wishes

KUYEADESOJI OLORUNFUNMI
Biography
Celebration

I am highly motivated in a remote working in isolation by cheering
working home setting. This gives your ideas.
a better work-life balance, less I am highly motivated in a remote
commute, stress, the time saving working home setting. This gives
that allows you to focus on a better work-life balance, less
priorities outside of work. I commute, stress, the time saving
possess a customizable office that allows you to focus on
that creates a comfortable office priorities outside of work. I
for me. The usual fewer possess a customizable office
interruptions, fewer office that creates a comfortable office
politics, and a quite nice level for me. The usual fewer
lead to my increase in motivation interruptions, fewer office
and productivity for work. The politics, and a quite nice level
commitment to clients per care lead to my increase in motivation
excellence with a positive and and productivity for work. The
empathetic manner. Also, being commitment to clients per care
locally independent and my excellence with a positive and
sustainability to research and empathetic manner. Also, being
ideating with the brand designs. locally independent and my
The ability to eat healthier also sustainability to research and
motivates great creative ideas in ideating with the brand designs.
you through brainstorming. The The ability to eat healthier also
high-tech-savvy equipment for motivates great creative ideas in
graphics motivates you for good you through brainstorming. The
productivity in the creative world. high-tech-savvy equipment for
Finally, the ability to get in touch graphics motivates you for good
with other team members to productivity in the creative world.
interact using technology like Finally, the ability to get in touch
zoom, google meet, WhatsApp, with other team members to
and others related to work would interact using technology like
motivate your ability not to be zoom, google meet, WhatsApp,

01

KUYEADESOJI OLORUNFUNMI
picture panorama
Celebration

01

KUYEADESOJI OLORUNFUNMI
picture panorama
Celebration

01

KUYEADESOJI OLORUNFUNMI
picture panorama
Celebration

01

KUYEADESOJI OLORUNFUNMI
picture panorama
Celebration

01

KUYEADESOJI OLORUNFUNMI
picture panorama
Celebration

01

KUYEADESOJI OLORUNFUNMI
picture panorama
Celebration

Yetunde's Husband with Children

01

KUYEADESOJI OLORUNFUNMI
picture panorama
Celebration

Rebecca Shobanjo’s Grandchilren

01

KUYEADESOJI OLORUNFUNMI
BIRTHDAY WISHES
Celebration

My wonderful lovely Big Brother

Today as you celebrate your 70th birthday, may you feel loved by all those around you. Happy
birthday, my wonderful lovely Big Brother. In my heart you will always remain precious. You are
the author of what I am today. God bless your new Age.

My wonderful lovely Big Brother

Today as you celebrate your 70th birthday, may you feel loved by all those around you. Happy
birthday, my wonderful lovely Big Brother. In my heart you will always remain precious. You are
the author of what I am today. God bless your new Age.

My wonderful lovely Big Brother

Today as you celebrate your 70th birthday, may you feel loved by all those around you. Happy
birthday, my wonderful lovely Big Brother. In my heart you will always remain precious. You are
the author of what I am today. God bless your new Age.

My wonderful lovely Big Brother

Today as you celebrate your 70th birthday, may you feel loved by all those around you. Happy
birthday, my wonderful lovely Big Brother. In my heart you will always remain precious. You are
the author of what I am today. God bless your new Age.

My wonderful lovely Big Brother

Today as you celebrate your 70th birthday, may you feel loved by all those around you. Happy
birthday, my wonderful lovely Big Brother. In my heart you will always remain precious. You are
the author of what I am today. God bless your new Age.

01

KUYEADESOJI OLORUNFUNMI
BIRTHDAY WISHES
Celebration

My wonderful lovely Big Brother

Today as you celebrate your 70th birthday, may you feel loved by all those around you. Happy
birthday, my wonderful lovely Big Brother. In my heart you will always remain precious. You are
the author of what I am today. God bless your new Age.

My wonderful lovely Big Brother

Today as you celebrate your 70th birthday, may you feel loved by all those around you. Happy
birthday, my wonderful lovely Big Brother. In my heart you will always remain precious. You are
the author of what I am today. God bless your new Age.

My wonderful lovely Big Brother

Today as you celebrate your 70th birthday, may you feel loved by all those around you. Happy
birthday, my wonderful lovely Big Brother. In my heart you will always remain precious. You are
the author of what I am today. God bless your new Age.

My wonderful lovely Big Brother

Today as you celebrate your 70th birthday, may you feel loved by all those around you. Happy
birthday, my wonderful lovely Big Brother. In my heart you will always remain precious. You are
the author of what I am today. God bless your new Age.

My wonderful lovely Big Brother

Today as you celebrate your 70th birthday, may you feel loved by all those around you. Happy
birthday, my wonderful lovely Big Brother. In my heart you will always remain precious. You are
the author of what I am today. God bless your new Age.

01

ReceptionGet Together 1. Arrival of Guests

2. Introduction of Distinguished Chairman

Programme 3. Opening Prayer
4. Chairperson's Opening Remark
KUYEADESOJI OLORUNFUNMI
5. Toast of the Celebrant

6. Menu! Menu!! Menu!!!
@ His 7. Photo Session

8. Vote of Thanks

9. Celebrant's thank you speech

10. Best wishes & Birthday song

Celebration 11. Closing Prayer
12. Dance! Dance!! Dance!!!

Appreciation

All praise, glory, honour and adoration to Almighty God for this day.
On behalf of Adesoji Olorunmi Kuye Family,
We hereby express our profound gratitude to the Archdecontry &
Vicar, the Clergy, Members of St. Barnabas' Church, and well wishers
for your moral, physical and financial support in making today's 70th
Birthday Celebration a huge success.
May God in His infinite Mercy Bless you, protect and be with you
always. Thanks and God bless.

Idupe

Ni oruko gbogbo Ebi mi Adesoji Olorunmi Kuye.
Mo dupe lowo Alufa wa Venerable O. O. Igbalajobi, Oluranlowo Alufa,
Awon Akawe Mimo, Egbe Akorin, Aluduru ati Adena.
Mo si tun dupe Gbogbo Omo Ijo Barnaba Mimo fun idide fun Adorin
Ojo ibi mi ti ase ni Ojo oni ni Oruko Jesu.
Oluwa a bukun gbogbo wa lapapo Ase, Oluwa jeki gbogbo wa se opo
odun laiye o. Ase. Adele bare, Arin kore, Afoya ibi. Amin.

Mission &Vision Statement of

Mission:

To present very Clergy and aity perfect in
Christ Jesus ( Colossians 1:28b)

Vision:

The mission shall be split into visions which include:
1. To make every member a matured Christians

(Discipleship) having strong faith in Jesus Christ
for salvation.
2. To make every Christian a soul winner (witnessing)
producing fruits that will abide.
3. To make the Word of God fully known
(knowledge), lived out (Life style), memorized, and
pray using the same.
4. To produce 'new wine' in the home and family life.
5. To enlighten and educate children and youth to
committedly serve the Lord and live for Him.
6. That all church workers would be developed and
encourage to minister out of conviction and not by
compulsion, vocationally not professionally.
7. To consolidate our financial investments and
break new grounds.

Slogan:

Christ in you!!!
The hope of Glory!!!

Denik: 0803 304 2473, 0803 468 2992


Click to View FlipBook Version