2. CALL TO WORSHIP/OPENING PAYER..3MINS PROCESSIONAL .1..Gbogbo aye, gbe Jesu ga. di Angel', e wole fun: E mu ade Oba Re wa, Se l'Oba awon oba. 2 . Ese l'Oba eyin Martyr, Ti npe ni pepe Re: Gbe gbongbo igi Jese ga, Se l'Oba awon oba. 3. Eyin iru omo Israel', Ti a ti rapada; E ki Eni t'O gba yin la, Se l'Oba awon oba. 4. Gbogbo eniyan elese Ranti 'banuje yin; E te 'kogun yin s'ese Re, Se l'Oba awon oba. 5. Ki gbogbo orile ede, Ni gbogbo agbaye; Ki won ki, “Kabiyesile” Se l'Oba awon oba. 6. Descant A ba le pel'awon t'orun, Lati ma juba Re; K'a bale jo jumo korin, Se l'Oba awon oba. Amin To Him all majesty ascribe, And crown Him Lord of all, To Him all majesty ascribe, And crown Him Lord of all. Verse 6 O that with yonder sacred throng, We at His feet may fall, We'll join the everlasting song, And crown Him Lord of all. We'll join the everlasting song, And crown Him Lord of all! Amen 1 2 1. PROCESSIONAL HYMN…GBOGBO AIYE GBE JESU GA....3MINUTES 2. CALL TO WORSHIP/OPENING PAYER..3MINS 3. INTROIT-OLORUN AIYE MI.4MINS...STARTS WITH SOLO BY CELEBRANT 4. OPENING HMYN—KINI NGO FUN OLORUN MI—4MIN 5. PRAISE WORSHIP—BAND—10MINS 6. BIBLE READING PSALM 136 CELEBRANT—4MINS 7. CHANT---AWA YIN O 8. SERMON 9. ANTHEM... MESSIAH BABA MI.. CHOIR 10 . HYMN BEFORE PRAYER SESSION..KNEELING... ALMIGHTY MAKER OF MY LIFE 11. PRAYER SESSION 12. HYMN AFTER PRAYER.. KNEELING... BE WITH ME LORD WHERE 'VER I GO 13. THE GRACE...REVEREND 14...FAMILY ANTHEM….NIPA IFE OLUGBALA 15. VOTE OF THANKS 16.. CLOSING HYMN..GO MY CHILDREN ... 17. BENEDICTION 18.. RECESSIONAL HYMN---MU MI DURO …BAND ITEM 12 KNEELING Order Of Service PROCESSIONAL HYMN GBO AIYE GBE JESU GA.
3 4 INTROIT OLORUN AIYE MISOLO CELEBRANT 1. OLORUN aiye mi Emi ni yo si O Ore Re l'o da mi L'o da mi si sibe Ayajo ibi mi tun de Ngo sure f'ojo t'a bi mi. 2. Ni gbogbo ojo mi Ki nwa laye fun O Ki gbogbo emi mi F'ope, iyin fun O Gbogbo ini at'iwa mi Y'o yin Eleda mi logo. DESCANT 3. Gbogbo pa emi mi Y'o je Tire nikan Gbogbo akoko mi Mo ya soto fun O Jo tun mi bi l'aworan Re Ngo si ma yin O titi aiye. 4. Mo nfe se ife Re B'angel' ti nse l'orun Ki ndatunbi n'nu Krist' Ki nri 'dariji gba Mo nfe mu 'fe pipe Re se K'ife Re ya mi si Mimo. DESCANT 5. Gba 'se na ba pari L'agbara igbagbo Tewogb' ayanfe Re Li akoko iku Pe mi sodo bi ti Mose Gbe emi mi s'afefe 're. Amin ubu Solutions God Of My Life, To Thee by Charles Wesley Song LyricsMore Songs Hymns 15 - For Believers, Rejoicing (189-264) by Charles Wesley 3 INTROIT OLORUN AIYE MI..STARTS WITH SOLO BY CELEBRANT. 1 GOD of my life, to thee My cheerful soul I raise! Thy goodness bade me be, And still prolongs my days; I see my natal hour return, And bless the day that I was born. 2 A clod of living earth, I glorify thy name, From whom alone my birth, And all my blessings, came, Creating and preserving grace Let all that is within me praise. 3 Long as I live beneath, To thee O let me live! To thee my every breath In thanks and praises give. Whate'er I have, whate'er I am, Shall magnify my Maker's name. 4 My soul and all its powers Thine, wholly thine, shall be; All, all my happy hours I consecrate to thee; Me to thine image now restore, And I shall praise thee evermore. 5 I wait thy will to do, As angels do in heaven; In Christ a creature new, Most graciously forgiven, I wait thy perfect will to prove, All sanctified by spotless love. 6 Then, when the work is done, The work of faith with power, Receive thy favoured son, In death's triumphant hour; Like Moses to thyself convey, And kiss my raptured soul away. Amen God Of My Life, To Thee by Charles Wesley Album: Hymns 15 - For Believers, Rejoicing (189-264) OPENING HYMN WITH BAND 1: Kini ngo fun Ọlọrun mi Fun gbogbo anu Rẹ?̀ Ngo gba ẹbun Rẹ,̀ ngo sì fi. Irẹlẹ̀bẽre sĩ. 2: Ago or'-ọfẹ igbala L' emi o f' ọpẹ gbà, Ngo fẹhinti ileri Rẹ,̀ Ngo sì wà f' ogo Rẹ.̀ 3: Loju awọn enia Rẹ̀ Ni ngo san ẹj̀ẹ́mi, Ngo f' ara mi on ìní mi Fi jọsin f' Ọlọrun. 4: Baba, gbogb' ohun ti mo ni, 'Wọ l' o fi jinki mi; Mo jẹ ọmọ Rẹ laiye yi, 'Wọ sì rà mi pada. 5: Ọwọ Rẹ l' o dá mi, l' o sì. Da mi n'dè n'nu ẹṣẹ; Anu Rẹ t' o tú idè mi Sì ti dè mi mọ Ọ. 6: Ọlọrun Oludande mi, Ngo mã kokiki Rẹ, Emi y'o rú ẹbọ iyin, Ngo kepè õkọ Rẹ.̀ 7: Ẹ f' iyin f' Ọlọrun ifẹ T' o f' ẹṣẹ mi jì mi, Titi ao pẹlu 'jọ toke. Kọ orin ti ọrun. AMIN 4. OPENING HYMN KINI UGO FUN OLORUN MI 5. PRAISE WORSHIP—BAND 6. BIBLE READING PSALM 136 CELEBRANT 7. CHANT-Awa Yin o AWA YIN O Awa Yin O, Olorun Awa njewo Re pe iwo ni oluwa Gbgbo aye fi ori ba le fun o Baba Aye titi lai Iwo ni eniti gbobo awon Angeli Nki gbe pe Orun ati gbogbo agbara Ti mbe ninu won Iwo ni eniti awon Kerubu ati awon Serafu Kigbe pe ni gba gbogbo pe. Mimo Mimo Mimo Oluwa Olorun awon omo ogun Orun oun aiyeKun fun ola nla/ ti o go Re Egbe awon Aposteli Ti o logo/ Yin o Ogba awon Woli Ti o dara, /Yin o Ogun awon Matyr Ti o dara /Yin o Ijo Mimo eniyan Olorun Ni gbogbo aye/ Nje wo o Re Baba/ en ola nla Ti Ko ni i pe kun Ati Omo Re nikansoso Olo la O lo 'to Emi Mi mo pelu Olutunu ni Kristi, iwo ni Oba Ogo Iwo ni Omo lailai ti Baba Nigbati iwo tewogba fun ara Re lati gba eniyan la O ko korira inu wundia Nigbati o segun oro iku tan O si ijoba orun sile fun gbobo Awon onigbagbo.
5 6 Baba/ en ola nla Ti Ko ni i pe kun Ati Omo Re nikansoso Olo la O lo 'to Emi Mi mo pelu Olutunu ni Kristi, iwo ni Oba Ogo Iwo ni Omo lailai ti Baba Nigbati iwo tewogba fun ara Re lati gba eniyan la O ko korira inu wundia Nigbati o segun oro iku tan O si ijoba orun sile fun gbobo Awon onigbagbo. Oluwa gba awon eniyan Re la Ki iwo ki o si fi Ibukun fun awon eniyan i ni Re J' O ba won Ki o si ma gbe won leke lailai Awa ngbe o ga Ni o jo jumo Awon si nfi ori bale ni Oru ko Re Titi aye/ ti ko ni pe kun. Fiyesini Oluwa Lati pa wa mo loni ni ailese Oluwa Sanu fun wa Sa a nu fun wa Olunwa, je ki anu Re ki o ma ba le wa Gegebi awa ti n gbeke wa le o Oluwa, Iwo ni mo Gbe ke le Lai ma je ki da mu.. 8. SERMON 9. ANTHEM... MESSIAH BABA MI.. CHOIR ALMIGHTY MAKER OF MY LIFE. 1.Almighty maker of my life! Teach to number all my days, Teach me to know how frail I am, And spend the remnant in Thy praise. 2.My days are shorter than a span, A little point my life appears; How frail at best is dying man! How vain are all his hopes and fears! 3.Vain my ambition, noise and show; Vain are the cares which rack my mind; I heap up treasures mixed with woe, And die and leave them all behind. DESCANT O make a nobler portion mine! My God, I bow before Thy throne; Earth's fleeting treasures I resign, And fix my hope on Thee alone. AMEN 10. HYMN BEFORE PRAYER KNEELING BE WITH ME LORD VERSE I Be with me, Lord, where'er I go; teach me what thou wouldst have me do; suggest whate'er I think or say; direct me in the narrow way. VERSE 2 Work in me, lest I harbor pride, lest I in my own strength confide; show me my weakness, let me see I have my power, my all, from thee. VERSE3 Enrich me always with thy love; My kind protection ever prove; Thy signet put upon my breast, And let thy Spirit on me rest. VERSE4 Assist and teach me how to pray; incline my nature to obey; what thou abhorrest let me flee, and only love what pleases thee. VERSE5 O may I never do my will, But thine and only thine fulfil; Let all my time and all my ways Be spent and ended to thy praise. AMEN THE GRACE.....REVEREND 12 KNEELING HYMN AFTER PRAYER SESSION BE WITH ME LORD. FAMILY ANTHEM Nipa ife Olugbala 1. Nipa ife olugbala ki yio si nkan Ojurere re ki pada ki yio si nkan Owon l'eje t'owo wa san Pipe ledidi or'ofe Agbara l'owo t'ogba ni Kole si nkan 2 Bi a wa ninu iponju ki yio si nkan Igbala kikun ni tawa ki yio si nkan Igbekele olorun dun, gbigbe ninu Kristi l'ere Emi sin so wa di mimo Kole si nkan DESCANT 3 Ojo ola yio dara ki yio si nkan Gbagbo le korin nnu ponji, ki yio si nkan Agbe kele 'fe baba wa Jesu fun wa l'ohun gbogbo Ni yiye tabi ni kiku Ko le si nkan Amin 14. FAMILY ANTHEM NIPA IFE OLUGBALA 11. PRAYER SESSION 13. THE GRACE...REVEREND 15. VOTE OF THANKS
7 8 Birthday Hearty Cheers! MRS OLUFUNMILAYO JOSEPHINE OYENUGA of Verse 1..ALL Go, my children, with my blessing, never alone. Waking, sleeping, I am with you; You are my own. In my love's baptismal river I have made you mine forever. Go, my children, with my blessing - You are my own. VERSE 2 F.. Go, my children, sins forgiven, M.. At peace and pure. F..Here, you learned how much I love you M..what I can cure. ALL Here you heard my dear Son's story; Here you touched him, saw his glory. Go, my children, sins forgiven, at peace and pure. VERSE 3 M..Go, my children, fed and nourished, F..Closer to me; M..Grow in love and love by serving, F.. joyful, and free. ALL Here, my Spirit's power filled you; and my tender comfort stilled you. Go, my children, fed and nourished, joyful and free. VERSE 4 ALL LOW..I the Lord will bless and keep you And give you peace; I the Lord will smile upon you And give you peace; LOUD..ALL...TWICE I the Lord will be your Father, Savior, Comforter, and Brother. Go, my children; I will keep you And give you peace. 16. CLOSING HYMN GO MY CHILDREN. B'o ba ni Jesu k'o dimu 11. Recessional Hymn Akokun 22 “B'o ba ni Jesu k'o dimu” B'o ba ni Jesu k'o dimu, K'o si toro imuduro, Jesu, Oluwa mi, Mu mi duro dopin. Mu mi duro, mu mi duro, Mu mi duro dopin, Jesu, Oluwa mi, Mu mi duro dopin. Ninu ofi-ola aiye, Pelu danwo arotele, Jesu, Oluwa mi, Mu mi duro dopin. Nigba 'banuje ile B'a d'ori okan mi kodo; Jesu, Oluwa mi, Mu mi duro dopin. Nigba wahal' aiye l'otun Idanwo Esu li osi, Jesu, Oluwa mi, Mu mi duro dopin. Nigba Esu gbe mi soke, T'o fe k'emi k'o teriba, Jesu, Oluwa mi, Mu mi duro dopin. Nigbat' o ku emi nikan, Ti ko si alabaro mo; Jesu, Oluwa mi, Mu mi duro dopin. Amin 18. RECESSIONAL HYMN MU MI DURO 17. BENEDICTION
9 10